ORIN DAFIDI 131:2-3

ORIN DAFIDI 131:2-3 YCE

Kàkà bẹ́ẹ̀, mo fi ara mi lọ́kàn balẹ̀, mo dákẹ́ jẹ́ẹ́, bí ọmọ ọwọ́ tíí dákẹ́ jẹ́ẹ́ láyà ìyá rẹ̀. Ọkàn mi balẹ̀ bíi ti ọmọ ọwọ́ tó dákẹ́ jẹ́ẹ́. Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ ní ìrètí ninu OLUWA, láti ìsinsìnyìí lọ ati títí laelae.