O. Daf 112:6-7

O. Daf 112:6-7 YBCV

Nitoriti a kì yio yi i nipò pada lailai: olododo yio wà ni iranti titi aiye. Kì yio bẹ̀ru ihin buburu: aiya rẹ̀ ti mu ọ̀na kan, o gbẹkẹle Oluwa.