O. Daf 112:6-7
O. Daf 112:6-7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitoriti a kì yio yi i nipò pada lailai: olododo yio wà ni iranti titi aiye. Kì yio bẹ̀ru ihin buburu: aiya rẹ̀ ti mu ọ̀na kan, o gbẹkẹle Oluwa.