O. Daf 107:13-14

O. Daf 107:13-14 YBCV

Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si gbà wọn ninu iṣẹ́ wọn. O mu wọn jade kuro ninu òkunkun ati ojiji ikú, o si fa ìde wọn ja.