O. Daf 107:13-14
O. Daf 107:13-14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si gbà wọn ninu iṣẹ́ wọn. O mu wọn jade kuro ninu òkunkun ati ojiji ikú, o si fa ìde wọn ja.