Owe 24:1-2

Owe 24:1-2 YBCV

IWỌ máṣe ilara si awọn enia buburu, bẹ̃ni ki o má si ṣe fẹ lati ba wọn gbe. Nitoriti aiya wọn ngbiro iparun, ète wọn si nsọ̀rọ ìwa-ika.