Owe 24:1-2
Owe 24:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
IWỌ máṣe ilara si awọn enia buburu, bẹ̃ni ki o má si ṣe fẹ lati ba wọn gbe. Nitoriti aiya wọn ngbiro iparun, ète wọn si nsọ̀rọ ìwa-ika.
Pín
Kà Owe 24IWỌ máṣe ilara si awọn enia buburu, bẹ̃ni ki o má si ṣe fẹ lati ba wọn gbe. Nitoriti aiya wọn ngbiro iparun, ète wọn si nsọ̀rọ ìwa-ika.