Luk 23:42-43

Luk 23:42-43 YBCV

O si wipe, Jesu, ranti mi nigbati iwọ ba de ijọba rẹ. Jesu si wi fun u pe, Lõtọ ni mo wi fun ọ, Loni ni iwọ o wà pẹlu mi ni Paradise.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ