Ẹk. Jer 3:55-57

Ẹk. Jer 3:55-57 YBCV

Emi kepe orukọ rẹ, Oluwa, lati iho jijin wá. Iwọ ti gbọ́ ohùn mi: máṣe se eti rẹ mọ si imikanlẹ mi, si igbe mi. Iwọ sunmọ itosi li ọjọ ti emi kigbe pè ọ: iwọ wipe: Má bẹ̀ru!