Ẹk. Jer 3:55-57
Ẹk. Jer 3:55-57 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi kepe orukọ rẹ, Oluwa, lati iho jijin wá. Iwọ ti gbọ́ ohùn mi: máṣe se eti rẹ mọ si imikanlẹ mi, si igbe mi. Iwọ sunmọ itosi li ọjọ ti emi kigbe pè ọ: iwọ wipe: Má bẹ̀ru!
Pín
Kà Ẹk. Jer 3