Job 1:1-2

Job 1:1-2 YBCV

ỌKUNRIN kan wà ni ilẹ Usi, orukọ ẹniti ijẹ Jobu; ọkunrin na si ṣe olõtọ, o duro ṣinṣin, ẹniti o si bẹ̀ru Ọlọrun, ti o si korira ìwa buburu. A si bi ọmọkunrin meje ati ọmọbinrin mẹta fun u.