Job 1:1-2
Job 1:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
ỌKUNRIN kan wà ni ilẹ Usi, orukọ ẹniti ijẹ Jobu; ọkunrin na si ṣe olõtọ, o duro ṣinṣin, ẹniti o si bẹ̀ru Ọlọrun, ti o si korira ìwa buburu. A si bi ọmọkunrin meje ati ọmọbinrin mẹta fun u.
Pín
Kà Job 1