Jak 5:1-2

Jak 5:1-2 YBCV

Ẹ wá nisisiyi, ẹnyin ọlọrọ̀, ẹ mã sọkun ki ẹ si mã pohunréré ẹkun nitori òṣi ti mbọ̀wá ta nyin. Ọrọ̀ nyin dibajẹ, kòkoro si ti jẹ̀ aṣọ nyin.