Jak 5:1-2
Jak 5:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ wá nisisiyi, ẹnyin ọlọrọ̀, ẹ mã sọkun ki ẹ si mã pohunréré ẹkun nitori òṣi ti mbọ̀wá ta nyin. Ọrọ̀ nyin dibajẹ, kòkoro si ti jẹ̀ aṣọ nyin.
Pín
Kà Jak 5Ẹ wá nisisiyi, ẹnyin ọlọrọ̀, ẹ mã sọkun ki ẹ si mã pohunréré ẹkun nitori òṣi ti mbọ̀wá ta nyin. Ọrọ̀ nyin dibajẹ, kòkoro si ti jẹ̀ aṣọ nyin.