Gẹn 26:34-35

Gẹn 26:34-35 YBCV

Esau si di ẹni ogoji ọdún nigbati o mu Juditi li aya, ọmọbinrin Beeri, ara Hitti, ati Baṣemati, ọmọbinrin Eloni, ara Hitti: Ohun ti o ṣe ibinujẹ fun Isaaki ati fun Rebeka.