Eks 22:21-23

Eks 22:21-23 YBCV

Iwọ kò gbọdọ ṣìka si alejò, bẹ̃ni iwọ kò gbọdọ ni i lara: nitoripe alejò li ẹnyin ti jẹ́ ni ilẹ Egipti. Ẹnyin kò gbọdọ jẹ opó ni ìya, tabi ọmọ alainibaba. Bi iwọ ba jẹ wọn ni ìyakiya, ti nwọn si kigbe pè mi, emi o gbọ́ igbe wọn nitõtọ.