ẸKISODU 22:21-23

ẸKISODU 22:21-23 YCE

“Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ pọ́n àlejò lójú tabi kí ó ni ín lára, nítorí pé ẹ̀yin náà ti jẹ́ àlejò rí ní ilẹ̀ Ijipti. Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ fìyà jẹ opó tabi aláìníbaba. Bí ẹnikẹ́ni bá fìyà jẹ wọ́n, tí wọ́n bá ké pè mí, dájúdájú n óo gbọ́ igbe wọn