Oni 7:8-9

Oni 7:8-9 YBCV

Opin nkan san jù ipilẹṣẹ rẹ̀ lọ: ati onisuru ọkàn jù ọlọkàn igberaga. Máṣe yara li ọkàn rẹ lati binu, nitoripe ibinu simi li aiya aṣiwère.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Oni 7:8-9

Oni 7:8-9 - Opin nkan san jù ipilẹṣẹ rẹ̀ lọ: ati onisuru ọkàn jù ọlọkàn igberaga.
Máṣe yara li ọkàn rẹ lati binu, nitoripe ibinu simi li aiya aṣiwère.Oni 7:8-9 - Opin nkan san jù ipilẹṣẹ rẹ̀ lọ: ati onisuru ọkàn jù ọlọkàn igberaga.
Máṣe yara li ọkàn rẹ lati binu, nitoripe ibinu simi li aiya aṣiwère.