Oni 7:8-9
Oni 7:8-9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Opin nkan san jù ipilẹṣẹ rẹ̀ lọ: ati onisuru ọkàn jù ọlọkàn igberaga. Máṣe yara li ọkàn rẹ lati binu, nitoripe ibinu simi li aiya aṣiwère.
Pín
Kà Oni 7Oni 7:8-9 Yoruba Bible (YCE)
Òpin nǹkan sàn ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ, sùúrù sì dára ju ìwà ìgbéraga lọ. Má máa yára bínú, nítorí àyà òmùgọ̀ ni ibinu dì sí.
Pín
Kà Oni 7