Oni 10:5-7

Oni 10:5-7 YBCV

Buburu kan mbẹ ti mo ri labẹ õrùn, bi ìṣina ti o ti ọdọ awọn ijoye wá. A gbe aṣiwère sipò ọlá, awọn ọlọrọ̀ si joko nipò ẹhin. Mo ri awọn ọmọ-ọdọ lori ẹṣin, ati awọn ọmọ-alade nrìn bi ọmọ-ọdọ ni ilẹ.