Oni 10:5-7
Oni 10:5-7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Buburu kan mbẹ ti mo ri labẹ õrùn, bi ìṣina ti o ti ọdọ awọn ijoye wá. A gbe aṣiwère sipò ọlá, awọn ọlọrọ̀ si joko nipò ẹhin. Mo ri awọn ọmọ-ọdọ lori ẹṣin, ati awọn ọmọ-alade nrìn bi ọmọ-ọdọ ni ilẹ.
Pín
Kà Oni 10