Oni 1:2-4

Oni 1:2-4 YBCV

Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni! Ere kili enia jẹ ninu gbogbo lãla rẹ̀ ti o ṣe labẹ õrùn? Iran kan lọ, iran miran si bọ̀: ṣugbọn aiye duro titi lai.