Oni 1:2-4
Oni 1:2-4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni! Ere kili enia jẹ ninu gbogbo lãla rẹ̀ ti o ṣe labẹ õrùn? Iran kan lọ, iran miran si bọ̀: ṣugbọn aiye duro titi lai.
Pín
Kà Oni 1Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni! Ere kili enia jẹ ninu gbogbo lãla rẹ̀ ti o ṣe labẹ õrùn? Iran kan lọ, iran miran si bọ̀: ṣugbọn aiye duro titi lai.