Oni 1:1-2

Oni 1:1-2 YBCV

Ọ̀RỌ oniwasu, ọmọ Dafidi, ti o jọba ni Jerusalemu. Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni!