Oni 1:1-2
Oni 1:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọ̀RỌ oniwasu, ọmọ Dafidi, ti o jọba ni Jerusalemu. Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni!
Pín
Kà Oni 1Ọ̀RỌ oniwasu, ọmọ Dafidi, ti o jọba ni Jerusalemu. Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni!