ORIN DAFIDI 6:6

ORIN DAFIDI 6:6 YCE

Ìkérora dá mi lágara: ní òròòru ni mò ń fi omijé rẹ ẹní mi; tí mò ń sunkún tí gbogbo ibùsùn mi ń tutù.