Agara ikerora mi da mi: li oru gbogbo li emi nmu ẹní mi fó li oju omi; emi fi omije mi rin ibusùn mi.
Ìkérora dá mi lágara: ní òròòru ni mò ń fi omijé rẹ ẹní mi; tí mò ń sunkún tí gbogbo ibùsùn mi ń tutù.
Agara ìkérora mi dá mi tán. Gbogbo òru ni mo wẹ ibùsùn mi pẹ̀lú ẹkún, mo sì fi omi rin ibùsùn mi pẹ̀lú omijé.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò