ORIN DAFIDI 135:13-14

ORIN DAFIDI 135:13-14 YCE

OLUWA, orúkọ rẹ yóo wà títí lae, òkìkí rẹ óo sì máa kàn títí ayé. OLUWA yóo dá àwọn eniyan rẹ̀ láre, yóo sì ṣàánú àwọn iranṣẹ rẹ̀.