ORIN DAFIDI 111:1

ORIN DAFIDI 111:1 YCE

Ẹ yin OLUWA! N óo dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA tọkàntọkàn, láàrin àwọn olódodo, ati ní àwùjọ àwọn eniyan.