ÌWÉ ÒWE 4:23-26

ÌWÉ ÒWE 4:23-26 YCE

Ṣọ́ra pẹlu èrò ọkàn rẹ, nítorí èrò ọkàn ni orísun ìyè. Má lọ́wọ́ ninu ọ̀rọ̀ ìsọkúsọ, sì jìnnà sí ọ̀rọ̀ àgàbàgebè. Jẹ́ kí ojú rẹ máa wo ọ̀kánkán, kí o sì kọjú sí ibi tí ò ń lọ tààrà. Kíyèsí ìrìn ẹsẹ̀ rẹ, gbogbo ọ̀nà rẹ yóo sì là.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún ÌWÉ ÒWE 4:23-26

ÌWÉ ÒWE 4:23-26 - Ṣọ́ra pẹlu èrò ọkàn rẹ,
nítorí èrò ọkàn ni orísun ìyè.
Má lọ́wọ́ ninu ọ̀rọ̀ ìsọkúsọ,
sì jìnnà sí ọ̀rọ̀ àgàbàgebè.
Jẹ́ kí ojú rẹ máa wo ọ̀kánkán,
kí o sì kọjú sí ibi tí ò ń lọ tààrà.
Kíyèsí ìrìn ẹsẹ̀ rẹ,
gbogbo ọ̀nà rẹ yóo sì là.ÌWÉ ÒWE 4:23-26 - Ṣọ́ra pẹlu èrò ọkàn rẹ,
nítorí èrò ọkàn ni orísun ìyè.
Má lọ́wọ́ ninu ọ̀rọ̀ ìsọkúsọ,
sì jìnnà sí ọ̀rọ̀ àgàbàgebè.
Jẹ́ kí ojú rẹ máa wo ọ̀kánkán,
kí o sì kọjú sí ibi tí ò ń lọ tààrà.
Kíyèsí ìrìn ẹsẹ̀ rẹ,
gbogbo ọ̀nà rẹ yóo sì là.ÌWÉ ÒWE 4:23-26 - Ṣọ́ra pẹlu èrò ọkàn rẹ,
nítorí èrò ọkàn ni orísun ìyè.
Má lọ́wọ́ ninu ọ̀rọ̀ ìsọkúsọ,
sì jìnnà sí ọ̀rọ̀ àgàbàgebè.
Jẹ́ kí ojú rẹ máa wo ọ̀kánkán,
kí o sì kọjú sí ibi tí ò ń lọ tààrà.
Kíyèsí ìrìn ẹsẹ̀ rẹ,
gbogbo ọ̀nà rẹ yóo sì là.