ỌBADAYA 1:2-3

ỌBADAYA 1:2-3 YCE

Ó sọ fún Edomu pé, “Wò ó, n óo sọ ọ́ di yẹpẹrẹ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù; gbogbo ayé pátá ni yóo máa fi ọ́ ṣẹ̀sín. Ìgbéraga rẹ ti tàn ọ́ jẹ, ìwọ tí ò ń gbé inú pàlàpálá òkúta, tí ibùgbé rẹ wà lórí òkè gíga, tí o sì ń wí ninu ọkàn rẹ pé, ‘Ta ni ó lè fà mí lulẹ̀?’