Oba 1:2-3
Oba 1:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Kiyesi i, mo ti sọ iwọ di kekere larin awọn keferi: iwọ di gigàn lọpọlọpọ. Irera aiya rẹ ti tàn ọ jẹ, iwọ ti ngbe inu pàlapála apáta, ibugbe ẹniti o ga: ti o nwi li ọkàn rẹ̀ pe, Tani yio mu mi sọkalẹ?
Pín
Kà Oba 1Oba 1:2-3 Yoruba Bible (YCE)
Ó sọ fún Edomu pé, “Wò ó, n óo sọ ọ́ di yẹpẹrẹ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù; gbogbo ayé pátá ni yóo máa fi ọ́ ṣẹ̀sín. Ìgbéraga rẹ ti tàn ọ́ jẹ, ìwọ tí ò ń gbé inú pàlàpálá òkúta, tí ibùgbé rẹ wà lórí òkè gíga, tí o sì ń wí ninu ọkàn rẹ pé, ‘Ta ni ó lè fà mí lulẹ̀?’
Pín
Kà Oba 1