ẸKÚN JEREMAYA 3:22-23

ẸKÚN JEREMAYA 3:22-23 YCE

Nítorí pé Ìfẹ́ OLUWA tí kì í yẹ̀ kò nípẹ̀kun, àánú rẹ̀ kò sì lópin; ọ̀tun ni wọ́n láràárọ̀, òtítọ́ rẹ̀ pọ̀.