JAKỌBU 1:2-3

JAKỌBU 1:2-3 YCE

Ẹ̀yin ará mi, ẹ kà á sí ayọ̀ gidi nígbà tí oríṣìíríṣìí ìdánwò bá dé ba yín. Kí ẹ mọ̀ pé ìdánwò igbagbọ yín ń mú kí ẹ ní ìfaradà.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú JAKỌBU 1:2-3