ISIKIẸLI 23:34
ISIKIẸLI 23:34 YCE
O óo jìyà ní àjẹtẹ́rùn, tóbẹ́ẹ̀ tí o óo máa fi àkúfọ́ àwo ìyà tí o bá jẹ ya ara rẹ lọ́mú. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”