Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Esek 23:34

Esek 23:34 Bibeli Mimọ (YBCV)

Iwọ o tilẹ mu u, iwọ o si fi ẹnu fa ọti jade, iwọ o si fọ apãdi na, iwọ o si fà ọmú ara rẹ tu, nitori mo ti sọ ọ, li Oluwa Ọlọrun wi.

Pín
Kà Esek 23

Esek 23:34 Yoruba Bible (YCE)

O óo jìyà ní àjẹtẹ́rùn, tóbẹ́ẹ̀ tí o óo máa fi àkúfọ́ àwo ìyà tí o bá jẹ ya ara rẹ lọ́mú. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Pín
Kà Esek 23

Esek 23:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (BMYO)

Ìwọ yóò mú un ni àmugbẹ; ìwọ yóò sì fọ sí wẹ́wẹ́ ìwọ yóò sì fa ọmú rẹ̀ ya. Èmi ti sọ̀rọ̀ ni OLúWA Olódùmarè wí.

Pín
Kà Esek 23
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò