ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 2:13

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 2:13 YCE

Mo wá rí i pé bí ìmọ́lẹ̀ ti dára ju òkùnkùn lọ ni ọgbọ́n dára ju ìwà wèrè lọ.