Oni 2:13
Oni 2:13 Yoruba Bible (YCE)
Mo wá rí i pé bí ìmọ́lẹ̀ ti dára ju òkùnkùn lọ ni ọgbọ́n dára ju ìwà wèrè lọ.
Pín
Kà Oni 2Oni 2:13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbana ni mo ri pe ọgbọ́n ta wère yọ, to iwọn bi imọlẹ ti ta òkunkun yọ.
Pín
Kà Oni 2