ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 16:6

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 16:6 YCE

Wọ́n gba ilẹ̀ Firigia ati Galatia kọjá. Ẹ̀mí Mímọ́ kò gbà wọ́n láàyè láti lọ waasu ọ̀rọ̀ Oluwa ní Esia.