Ìṣe àwọn Aposteli 16:6

Ìṣe àwọn Aposteli 16:6 BMYO

Wọ́n sì la agbègbè Frigia já, àti Galatia, nítorí tí Ẹ̀mí Mímọ́ kọ̀ fún wọn láti sọ ọ̀rọ̀ náà ni Asia.