Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 8

1

Saamu 8:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

kí ni ènìyàn tí ìwọ ń rò nípa rẹ̀, àní ọmọ ènìyàn tí ìwọ ń ṣe ìtọ́jú rẹ̀?

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 8:4

2

Saamu 8:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nígbà tí mo ro ọ̀run rẹ, iṣẹ́ ìka rẹ, òṣùpá àti ìràwọ̀, tí ìwọ tí gbé kalẹ̀

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 8:3

3

Saamu 8:5-6

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìwọ ṣe é ní onírẹ̀lẹ̀ díẹ̀ ju Ọlọ́run lọ, ìwọ sì dé e ní adé ògo àti ọlá. Ìwọ mú un jẹ ọba lórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ; ìwọ sì fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 8:5-6

4

Saamu 8:9

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA, Olúwa wa, orúkọ rẹ ti ní ìyìn tó ní gbogbo ayé!

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 8:9

5

Saamu 8:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA, Olúwa wa, orúkọ rẹ̀ ti ní ìyìn tó ní gbogbo ayé! Ìwọ ti gbé ògo rẹ ga ju àwọn ọ̀run lọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 8:1

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 8

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest