Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 9

1

Saamu 9:10

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Àwọn tí ó mọ orúkọ rẹ yóò gbẹ́kẹ̀lé ọ, nítorí, OLúWA, kò kọ àwọn tó ń wá a sílẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 9:10

2

Saamu 9:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Èmi ó yìn ọ́, OLúWA, pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi; èmi ó sọ ti ìyanu rẹ gbogbo.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 9:1

3

Saamu 9:9

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA ni ààbò fún àwọn tí a ni lára, ibi ìsádi ní àkókò ìpọ́njú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 9:9

4

Saamu 9:2

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Inú mi yóò dùn, èmi yóò sì yọ̀ nínú rẹ; èmi ó kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ, Ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 9:2

5

Saamu 9:8

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Òun yóò sì ṣe ìdájọ́ ayé ní òdodo; yóò ṣe àkóso ènìyàn pẹ̀lú òdodo.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 9:8

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 9

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest