Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 7

1

Saamu 7:17

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Èmi ó fi ọpẹ́ fún OLúWA nítorí òdodo rẹ̀, èmi ó kọrin ìyìn sí OLúWA Ọ̀gá-ògo jùlọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 7:17

2

Saamu 7:10

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ààbò mi ń bẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run, ẹni tí ń ṣe ìgbàlà òtítọ́ ní àyà.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 7:10

3

Saamu 7:11

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ọlọ́run ni onídàájọ́ òtítọ́, Ọlọ́run tí ń sọ ìrunú rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 7:11

4

Saamu 7:9

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ọlọ́run Olódodo, Ẹni tí ó ń wo inú àti ọkàn, tí ó ń mú òpin sí ìwà ipá ẹni búburú tí ó sì ń pa àwọn olódodo mọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 7:9

5

Saamu 7:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA Ọlọ́run mi, ààbò mi wà nínú rẹ; gba mí là kí o sì tú mi sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tó ń lé mi

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 7:1

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 7

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest