Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

O. Daf 94:18

O. Daf 94:18 Bibeli Mimọ (YBCV)

Nigbati mo wipe, Ẹsẹ mi yọ́; Oluwa, ãnu rẹ dì mi mu.

Pín
Kà O. Daf 94

O. Daf 94:18 Yoruba Bible (YCE)

Nígbà tí mo rò pé, “Ẹsẹ̀ mi ti yọ̀,” OLUWA, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ni ó gbé mi ró.

Pín
Kà O. Daf 94

O. Daf 94:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Nígbà tí mo sọ pé “Ẹsẹ̀ mi ń yọ̀”, OLúWA, ìfẹ́ rẹ̀ ni ó tì mí lẹ́yìn.

Pín
Kà O. Daf 94

O. Daf 94:18

O. Daf 94:18 YBCV
Pín
Kà Orí tí ó kún
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò