Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 58

1

ORIN DAFIDI 58:11

Yoruba Bible

YCE

Àwọn eniyan yóo wí nígbà náà pé, “Nítòótọ́, èrè ń bẹ fún olódodo; nítòótọ́, Ọlọrun ń bẹ tí ń ṣe ìdájọ́ ayé.”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 58:11

2

ORIN DAFIDI 58:3

Yoruba Bible

YCE

Láti inú oyún ni àwọn eniyan burúkú ti ṣìnà, láti ọjọ́ tí a ti bí wọn ni wọ́n tí ń ṣìṣe, tí wọn ń purọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 58:3

3

ORIN DAFIDI 58:1-2

Yoruba Bible

YCE

Ǹjẹ́ ìpinnu tí ẹ̀ ń ṣe tọ̀nà, ẹ̀yin aláṣẹ? Ǹjẹ́ ẹ̀ ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan ní ọ̀nà ẹ̀tọ́? Rárá o! Ibi ni ẹ̀ ń fi ọkàn yín rò, iṣẹ́ burúkú ni ẹ sì ń fi ọwọ́ yín ṣe láyé.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 58:1-2

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest