ORIN DAFIDI 58:11

ORIN DAFIDI 58:11 YCE

Àwọn eniyan yóo wí nígbà náà pé, “Nítòótọ́, èrè ń bẹ fún olódodo; nítòótọ́, Ọlọrun ń bẹ tí ń ṣe ìdájọ́ ayé.”