Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 59

1

ORIN DAFIDI 59:16

Yoruba Bible

YCE

Ṣugbọn èmi ó kọrin ìyìn agbára rẹ; n óo kọrin sókè lówùúrọ̀, nípa ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀. Nítorí ìwọ ni o ti jẹ́ odi mi ìwọ sì ni ààbò mi nígbà ìpọ́njú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 59:16

2

ORIN DAFIDI 59:17

Yoruba Bible

YCE

Ọlọrun, agbára mi, n óo kọ orin ìyìn fún ọ, nítorí ìwọ, Ọlọrun, ni odi mi, Ọlọrun tí ó ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn mí.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 59:17

3

ORIN DAFIDI 59:9-10

Yoruba Bible

YCE

Ọlọrun, agbára mi, ojú rẹ ni mò ń wò, nítorí ìwọ, Ọlọrun, ni odi mi. Ọlọrun mi óo wá sọ́dọ̀ mi ninu ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀; Ọlọrun óo fún mi ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá mi.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 59:9-10

4

ORIN DAFIDI 59:1

Yoruba Bible

YCE

Gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi, Ọlọrun mi; dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn tí ó gbógun tì mí.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 59:1

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest