Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 4

1

ORIN DAFIDI 4:8

Yoruba Bible

YCE

N óo dùbúlẹ̀, n óo sì sùn ní alaafia, nítorí ìwọ OLUWA nìkan ni o mú mi wà láìléwu.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 4:8

2

ORIN DAFIDI 4:4

Yoruba Bible

YCE

Bí ó ti wù kí ẹ bínú tó, ẹ má dẹ́ṣẹ̀; ẹ bá ọkàn yín sọ̀rọ̀ lórí ibùsùn yín, kí ẹ sì dákẹ́ jẹ́ẹ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 4:4

3

ORIN DAFIDI 4:1

Yoruba Bible

YCE

Dá mi lóhùn nígbà tí mo bá pè ọ́, Ọlọrun mi olùdániláre. Ìwọ ni o yọ mí nígbà tí mo wà ninu ìpọ́njú, ṣàánú mi, kí o sì gbọ́ adura mi.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 4:1

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ORIN DAFIDI 4

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò