Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

O. Daf 4:4

O. Daf 4:4 Bibeli Mimọ (YBCV)

Ẹ duro ninu ẹ̀ru, ẹ má si ṣe ṣẹ̀; ẹ ba ọkàn nyin sọ̀rọ lori ẹní nyin, ki ẹ si duro jẹ.

Pín
Kà O. Daf 4

O. Daf 4:4 Yoruba Bible (YCE)

Bí ó ti wù kí ẹ bínú tó, ẹ má dẹ́ṣẹ̀; ẹ bá ọkàn yín sọ̀rọ̀ lórí ibùsùn yín, kí ẹ sì dákẹ́ jẹ́ẹ́.

Pín
Kà O. Daf 4

O. Daf 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Ẹ bínú ẹ má ṣe ṣẹ̀; Nígbà tí ẹ bá wà lórí ibùsùn yín, ẹ bá ọkàn yín sọ̀rọ̀, kí ó sì dákẹ́ jẹ́.

Pín
Kà O. Daf 4
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò