ORIN DAFIDI 4:8

ORIN DAFIDI 4:8 YCE

N óo dùbúlẹ̀, n óo sì sùn ní alaafia, nítorí ìwọ OLUWA nìkan ni o mú mi wà láìléwu.